Quran with Yoruba translation - Surah Ar-Rahman ayat 27 - الرَّحمٰن - Page - Juz 27
﴿وَيَبۡقَىٰ وَجۡهُ رَبِّكَ ذُو ٱلۡجَلَٰلِ وَٱلۡإِكۡرَامِ ﴾
[الرَّحمٰن: 27]
﴿ويبقى وجه ربك ذو الجلال والإكرام﴾ [الرَّحمٰن: 27]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ojú Olúwa rẹ, Atóbi, Alápọ̀n-ọ́nlé sì máa wà títí láéláé |