Quran with Yoruba translation - Surah Ar-Rahman ayat 35 - الرَّحمٰن - Page - Juz 27
﴿يُرۡسَلُ عَلَيۡكُمَا شُوَاظٞ مِّن نَّارٖ وَنُحَاسٞ فَلَا تَنتَصِرَانِ ﴾
[الرَّحمٰن: 35]
﴿يرسل عليكما شواظ من نار ونحاس فلا تنتصران﴾ [الرَّحمٰن: 35]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n máa ju ẹ̀ta-pàrà iná àti ẹ̀ta-pàrà idẹ lé ẹ̀yin méjèèjì lórí, ẹ̀yin méjèèjì kò sì lè ran’ra yín lọ́wọ́ |