Quran with Yoruba translation - Surah Ar-Rahman ayat 41 - الرَّحمٰن - Page - Juz 27
﴿يُعۡرَفُ ٱلۡمُجۡرِمُونَ بِسِيمَٰهُمۡ فَيُؤۡخَذُ بِٱلنَّوَٰصِي وَٱلۡأَقۡدَامِ ﴾
[الرَّحمٰن: 41]
﴿يعرف المجرمون بسيماهم فيؤخذ بالنواصي والأقدام﴾ [الرَّحمٰن: 41]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n máa mọ àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ pẹ̀lú àmì ara wọn. Wọ́n sì máa fi àásó orí àti ẹsẹ̀ gbá wọn mú |