Quran with Yoruba translation - Surah Al-Waqi‘ah ayat 65 - الوَاقِعة - Page - Juz 27
﴿لَوۡ نَشَآءُ لَجَعَلۡنَٰهُ حُطَٰمٗا فَظَلۡتُمۡ تَفَكَّهُونَ ﴾
[الوَاقِعة: 65]
﴿لو نشاء لجعلناه حطاما فظلتم تفكهون﴾ [الوَاقِعة: 65]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Tí A bá fẹ́ ni, Àwa ìbá sọ ọ́ di gbígbẹ, ẹ̀yin yó sì máa ṣèèmọ̀ (tí ẹ óò máa ká àbámọ̀) |