Quran with Yoruba translation - Surah Al-Waqi‘ah ayat 91 - الوَاقِعة - Page - Juz 27
﴿فَسَلَٰمٞ لَّكَ مِنۡ أَصۡحَٰبِ ٱلۡيَمِينِ ﴾
[الوَاقِعة: 91]
﴿فسلام لك من أصحاب اليمين﴾ [الوَاقِعة: 91]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni àlàáfíà ni fún ọ láààrin àwọn èrò ọwọ́ ọ̀tún |