×

Ti won ba si pe o ni opuro, so nigba naa pe: 6:147 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-An‘am ⮕ (6:147) ayat 147 in Yoruba

6:147 Surah Al-An‘am ayat 147 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-An‘am ayat 147 - الأنعَام - Page - Juz 8

﴿فَإِن كَذَّبُوكَ فَقُل رَّبُّكُمۡ ذُو رَحۡمَةٖ وَٰسِعَةٖ وَلَا يُرَدُّ بَأۡسُهُۥ عَنِ ٱلۡقَوۡمِ ٱلۡمُجۡرِمِينَ ﴾
[الأنعَام: 147]

Ti won ba si pe o ni opuro, so nigba naa pe: "Oluwa yin ni Onikee to gbooro. Ko si si eni t’o le gbe iya Re kuro lori ijo elese

❮ Previous Next ❯

ترجمة: فإن كذبوك فقل ربكم ذو رحمة واسعة ولا يرد بأسه عن القوم, باللغة اليوربا

﴿فإن كذبوك فقل ربكم ذو رحمة واسعة ولا يرد بأسه عن القوم﴾ [الأنعَام: 147]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Tí wọ́n bá sì pè ọ́ ní òpùrọ́, sọ nígbà náà pé: "Olúwa yín ni Oníkẹ̀ẹ́ tó gbòòrò. Kò sì sí ẹni t’ó lè gbé ìyà Rẹ̀ kúrò lórí ìjọ ẹlẹ́ṣẹ̀
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek