Quran with Yoruba translation - Surah Al-An‘am ayat 28 - الأنعَام - Page - Juz 7
﴿بَلۡ بَدَا لَهُم مَّا كَانُواْ يُخۡفُونَ مِن قَبۡلُۖ وَلَوۡ رُدُّواْ لَعَادُواْ لِمَا نُهُواْ عَنۡهُ وَإِنَّهُمۡ لَكَٰذِبُونَ ﴾
[الأنعَام: 28]
﴿بل بدا لهم ما كانوا يخفون من قبل ولو ردوا لعادوا لما﴾ [الأنعَام: 28]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Kò rí bẹ́ẹ̀, ohun tí wọ́n ń fi pamọ́ ṣíwájú ti hàn sí wọn ni. Tí ó bá jẹ́ pé A bá dá wọn padà (sílé ayé), wọn yóò kúkú padà síbi ohun tí A kọ̀ fún wọn. Dájúdájú òpùrọ́ mà ni wọ́n |