Quran with Yoruba translation - Surah Al-An‘am ayat 29 - الأنعَام - Page - Juz 7
﴿وَقَالُوٓاْ إِنۡ هِيَ إِلَّا حَيَاتُنَا ٱلدُّنۡيَا وَمَا نَحۡنُ بِمَبۡعُوثِينَ ﴾
[الأنعَام: 29]
﴿وقالوا إن هي إلا حياتنا الدنيا وما نحن بمبعوثين﴾ [الأنعَام: 29]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n wí pé: "Kí ni (ó tún jẹ́ ìṣẹ̀mí ọ̀run) bí kò ṣe ìṣẹ̀mí wa nílé ayé; Wọn kò sì níí gbé wa dìde (ní ọ̀run) |