Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mumtahanah ayat 5 - المُمتَحنَة - Page - Juz 28
﴿رَبَّنَا لَا تَجۡعَلۡنَا فِتۡنَةٗ لِّلَّذِينَ كَفَرُواْ وَٱغۡفِرۡ لَنَا رَبَّنَآۖ إِنَّكَ أَنتَ ٱلۡعَزِيزُ ٱلۡحَكِيمُ ﴾
[المُمتَحنَة: 5]
﴿ربنا لا تجعلنا فتنة للذين كفروا واغفر لنا ربنا إنك أنت العزيز﴾ [المُمتَحنَة: 5]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Olúwa wa, má ṣe wá ní àdánwò fún àwọn t’ó ṣàì gbàgbọ́. Foríjìn wá, Olúwa wa. Dájúdájú Ìwọ ni Alágbára, Ọlọ́gbọ́n |