Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mulk ayat 9 - المُلك - Page - Juz 29
﴿قَالُواْ بَلَىٰ قَدۡ جَآءَنَا نَذِيرٞ فَكَذَّبۡنَا وَقُلۡنَا مَا نَزَّلَ ٱللَّهُ مِن شَيۡءٍ إِنۡ أَنتُمۡ إِلَّا فِي ضَلَٰلٖ كَبِيرٖ ﴾
[المُلك: 9]
﴿قالوا بلى قد جاءنا نذير فكذبنا وقلنا ما نـزل الله من شيء﴾ [المُلك: 9]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọn yóò wí pé: "Rárá, dájúdájú olùkìlọ̀ kan ti wá bá wa, ṣùgbọ́n a pè é ní òpùrọ́. A sì wí pé Allāhu kò sọ n̄ǹkan kan kalẹ̀. Kí ni ẹ̀yin bí kò ṣe pé ẹ wà nínú ìṣìnà t’ó tóbi |