Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mulk ayat 10 - المُلك - Page - Juz 29
﴿وَقَالُواْ لَوۡ كُنَّا نَسۡمَعُ أَوۡ نَعۡقِلُ مَا كُنَّا فِيٓ أَصۡحَٰبِ ٱلسَّعِيرِ ﴾
[المُلك: 10]
﴿وقالوا لو كنا نسمع أو نعقل ما كنا في أصحاب السعير﴾ [المُلك: 10]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n tún wí pé: "Tí ó bá jẹ́ pé a gbọ́ràn ni tàbí pé a ṣe làákàyè ni, àwa kò níí wà nínú èrò inú Iná jíjò |