Quran with Yoruba translation - Surah Al-Qalam ayat 32 - القَلَم - Page - Juz 29
﴿عَسَىٰ رَبُّنَآ أَن يُبۡدِلَنَا خَيۡرٗا مِّنۡهَآ إِنَّآ إِلَىٰ رَبِّنَا رَٰغِبُونَ ﴾
[القَلَم: 32]
﴿عسى ربنا أن يبدلنا خيرا منها إنا إلى ربنا راغبون﴾ [القَلَم: 32]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ó ṣeé ṣe kí Olúwa wa fi èyí t’ó dára ju èyí lọ pààrọ̀ rẹ̀ fún wa. Dájúdájú ọ̀dọ̀ Olúwa wa ni àwa ń rokàn oore sí |