Quran with Yoruba translation - Surah Al-Qalam ayat 31 - القَلَم - Page - Juz 29
﴿قَالُواْ يَٰوَيۡلَنَآ إِنَّا كُنَّا طَٰغِينَ ﴾
[القَلَم: 31]
﴿قالوا ياويلنا إنا كنا طاغين﴾ [القَلَم: 31]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n wí pé: "Ègbé wa ò! Dájúdájú àwa jẹ́ olùtayọ-ẹnu àlà |