Quran with Yoruba translation - Surah Al-Qalam ayat 33 - القَلَم - Page - Juz 29
﴿كَذَٰلِكَ ٱلۡعَذَابُۖ وَلَعَذَابُ ٱلۡأٓخِرَةِ أَكۡبَرُۚ لَوۡ كَانُواْ يَعۡلَمُونَ ﴾
[القَلَم: 33]
﴿كذلك العذاب ولعذاب الآخرة أكبر لو كانوا يعلمون﴾ [القَلَم: 33]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Báyẹn ni ìyà náà ṣe rí (fún wọn). Ìyà ọ̀run sì tóbi jùlọ, tí ó bá jẹ́ pé wọ́n mọ̀ |