Quran with Yoruba translation - Surah Al-haqqah ayat 24 - الحَاقة - Page - Juz 29
﴿كُلُواْ وَٱشۡرَبُواْ هَنِيٓـَٔۢا بِمَآ أَسۡلَفۡتُمۡ فِي ٱلۡأَيَّامِ ٱلۡخَالِيَةِ ﴾
[الحَاقة: 24]
﴿كلوا واشربوا هنيئا بما أسلفتم في الأيام الخالية﴾ [الحَاقة: 24]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹ jẹ, kí ẹ sì mu pẹ̀lú ìgbàdún nítorí ohun tí ẹ tì síwájú nínú àwọn ọjọ́ tí ó ti ré kọjá |