Quran with Yoruba translation - Surah Al-haqqah ayat 25 - الحَاقة - Page - Juz 29
﴿وَأَمَّا مَنۡ أُوتِيَ كِتَٰبَهُۥ بِشِمَالِهِۦ فَيَقُولُ يَٰلَيۡتَنِي لَمۡ أُوتَ كِتَٰبِيَهۡ ﴾
[الحَاقة: 25]
﴿وأما من أوتي كتابه بشماله فيقول ياليتني لم أوت كتابيه﴾ [الحَاقة: 25]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ní ti ẹni tí wọ́n bá sì fún ní tírà rẹ̀ ní ọwọ́ òsì rẹ̀, ó máa wí pé: "Háà! Kí wọ́n sì má fún mi ni tírà mi! méjéèjì ló máa ṣẹlẹ̀ sí wọn nítorí pé ọwọ́ òsì ni aláìgbàgbọ́ máa tì bọ inú igbá-àyà rẹ̀ bọ́ sí ẹ̀yìn rẹ̀ láti fi gba ìwé iṣẹ́ rẹ̀ |