Quran with Yoruba translation - Surah Al-haqqah ayat 9 - الحَاقة - Page - Juz 29
﴿وَجَآءَ فِرۡعَوۡنُ وَمَن قَبۡلَهُۥ وَٱلۡمُؤۡتَفِكَٰتُ بِٱلۡخَاطِئَةِ ﴾
[الحَاقة: 9]
﴿وجاء فرعون ومن قبله والمؤتفكات بالخاطئة﴾ [الحَاقة: 9]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Fir‘aon àti àwọn t’ó ṣíwájú rẹ̀ àti àwọn ìlú tí wọ́n dojú rẹ̀ bolẹ̀ dé pẹ̀lú àwọn àṣìṣe |