Quran with Yoruba translation - Surah Al-A‘raf ayat 106 - الأعرَاف - Page - Juz 9
﴿قَالَ إِن كُنتَ جِئۡتَ بِـَٔايَةٖ فَأۡتِ بِهَآ إِن كُنتَ مِنَ ٱلصَّٰدِقِينَ ﴾
[الأعرَاف: 106]
﴿قال إن كنت جئت بآية فأت بها إن كنت من الصادقين﴾ [الأعرَاف: 106]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Fir‘aon) wí pé: “Tí o bá jẹ́ ẹni t’ó mú àmì kan wá, mú un jáde tí ìwọ bá wà nínú àwọn olódodo.” |