Quran with Yoruba translation - Surah Al-A‘raf ayat 16 - الأعرَاف - Page - Juz 8
﴿قَالَ فَبِمَآ أَغۡوَيۡتَنِي لَأَقۡعُدَنَّ لَهُمۡ صِرَٰطَكَ ٱلۡمُسۡتَقِيمَ ﴾
[الأعرَاف: 16]
﴿قال فبما أغويتني لأقعدن لهم صراطك المستقيم﴾ [الأعرَاف: 16]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Èṣù) wí pé: "Fún wí pé O ti fi mí sínú anù, èmi yóò jókòó dè wọ́n ní ọ̀nà tààrà Rẹ |