Quran with Yoruba translation - Surah Al-A‘raf ayat 21 - الأعرَاف - Page - Juz 8
﴿وَقَاسَمَهُمَآ إِنِّي لَكُمَا لَمِنَ ٱلنَّٰصِحِينَ ﴾
[الأعرَاف: 21]
﴿وقاسمهما إني لكما لمن الناصحين﴾ [الأعرَاف: 21]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ó sì búra fún àwọn méjèèjì pé: "Dájúdájú èmi wà nínú àwọn onímọ̀ràn fún ẹ̀yin méjèèjì |