Quran with Yoruba translation - Surah Al-A‘raf ayat 60 - الأعرَاف - Page - Juz 8
﴿قَالَ ٱلۡمَلَأُ مِن قَوۡمِهِۦٓ إِنَّا لَنَرَىٰكَ فِي ضَلَٰلٖ مُّبِينٖ ﴾
[الأعرَاف: 60]
﴿قال الملأ من قومه إنا لنراك في ضلال مبين﴾ [الأعرَاف: 60]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àwọn àgbààgbà nínú ìjọ rẹ̀ wí pé: "Dájúdájú àwa ń rí ọ pé o wà nínú ìṣìnà pọ́nńbélé |