Quran with Yoruba translation - Surah Al-Jinn ayat 26 - الجِن - Page - Juz 29
﴿عَٰلِمُ ٱلۡغَيۡبِ فَلَا يُظۡهِرُ عَلَىٰ غَيۡبِهِۦٓ أَحَدًا ﴾
[الجِن: 26]
﴿عالم الغيب فلا يظهر على غيبه أحدا﴾ [الجِن: 26]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Onímọ̀-ìkọ̀kọ̀, kò sì fi (ìmọ̀) ìkọ̀kọ̀ Rẹ̀ han ẹnì kan |