Quran with Yoruba translation - Surah Al-Muzzammil ayat 11 - المُزمل - Page - Juz 29
﴿وَذَرۡنِي وَٱلۡمُكَذِّبِينَ أُوْلِي ٱلنَّعۡمَةِ وَمَهِّلۡهُمۡ قَلِيلًا ﴾
[المُزمل: 11]
﴿وذرني والمكذبين أولي النعمة ومهلهم قليلا﴾ [المُزمل: 11]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Fi Mí dá àwọn olùpe-òdodo-nírọ́, àwọn ọlọ́rọ̀. Kí o sì lọ́ra fún wọn fún ìgbà díẹ̀ |