Quran with Yoruba translation - Surah Al-Muzzammil ayat 10 - المُزمل - Page - Juz 29
﴿وَٱصۡبِرۡ عَلَىٰ مَا يَقُولُونَ وَٱهۡجُرۡهُمۡ هَجۡرٗا جَمِيلٗا ﴾
[المُزمل: 10]
﴿واصبر على ما يقولون واهجرهم هجرا جميلا﴾ [المُزمل: 10]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Kí o sì ṣe sùúrù lórí ohun tí wọ́n ń wí. Pa wọ́n tì ní ìpatì t’ó rẹwà |