Quran with Yoruba translation - Surah Al-Muzzammil ayat 19 - المُزمل - Page - Juz 29
﴿إِنَّ هَٰذِهِۦ تَذۡكِرَةٞۖ فَمَن شَآءَ ٱتَّخَذَ إِلَىٰ رَبِّهِۦ سَبِيلًا ﴾
[المُزمل: 19]
﴿إن هذه تذكرة فمن شاء اتخذ إلى ربه سبيلا﴾ [المُزمل: 19]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú èyí ni ìrántí. Nítorí náà, ẹni tí ó bá fẹ́ kí ó mú ojú ọ̀nà kan tọ̀ dé ọ̀dọ̀ Olúwa rẹ̀ |