Quran with Yoruba translation - Surah Al-Muzzammil ayat 18 - المُزمل - Page - Juz 29
﴿ٱلسَّمَآءُ مُنفَطِرُۢ بِهِۦۚ كَانَ وَعۡدُهُۥ مَفۡعُولًا ﴾
[المُزمل: 18]
﴿السماء منفطر به كان وعده مفعولا﴾ [المُزمل: 18]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Sánmọ̀ sì máa fàya pẹ́rẹpẹ̀rẹ nínú rẹ̀. Àdéhùn Rẹ̀ jẹ́ ohun tí ó máa ṣẹ |