Quran with Yoruba translation - Surah Al-Muzzammil ayat 9 - المُزمل - Page - Juz 29
﴿رَّبُّ ٱلۡمَشۡرِقِ وَٱلۡمَغۡرِبِ لَآ إِلَٰهَ إِلَّا هُوَ فَٱتَّخِذۡهُ وَكِيلٗا ﴾
[المُزمل: 9]
﴿رب المشرق والمغرب لا إله إلا هو فاتخذه وكيلا﴾ [المُزمل: 9]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Olúwa ibùyọ òòrùn àti ibùwọ̀ òòrùn, kò sí ọlọ́hun tí ìjọ́sìn tọ́ sí àfi Òun. Nítorí náà, mú Un ní Aláfẹ̀yìntì |