Quran with Yoruba translation - Surah Al-Insan ayat 7 - الإنسَان - Page - Juz 29
﴿يُوفُونَ بِٱلنَّذۡرِ وَيَخَافُونَ يَوۡمٗا كَانَ شَرُّهُۥ مُسۡتَطِيرٗا ﴾
[الإنسَان: 7]
﴿يوفون بالنذر ويخافون يوما كان شره مستطيرا﴾ [الإنسَان: 7]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n ń mú ẹ̀jẹ́ wọn ṣẹ. Wọ́n sì ń páyà ọjọ́ kan, tí aburú rẹ̀ jẹ́ ohun tí ó máa fọ́nká gan-an |