Quran with Yoruba translation - Surah An-Naba’ ayat 39 - النَّبَإ - Page - Juz 30
﴿ذَٰلِكَ ٱلۡيَوۡمُ ٱلۡحَقُّۖ فَمَن شَآءَ ٱتَّخَذَ إِلَىٰ رَبِّهِۦ مَـَٔابًا ﴾
[النَّبَإ: 39]
﴿ذلك اليوم الحق فمن شاء اتخذ إلى ربه مآبا﴾ [النَّبَإ: 39]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ìyẹn ni ọjọ́ òdodo. Nítorí náà, ẹni tí ó bá fẹ́ kí ó mú ọ̀nà tó máa gbà ṣẹ́rí padà sí ọ̀dọ̀ Olúwa rẹ̀ pọ̀n (ní ti ìronúpìwàdà) |