Quran with Yoruba translation - Surah An-Nazi‘at ayat 25 - النَّازعَات - Page - Juz 30
﴿فَأَخَذَهُ ٱللَّهُ نَكَالَ ٱلۡأٓخِرَةِ وَٱلۡأُولَىٰٓ ﴾
[النَّازعَات: 25]
﴿فأخذه الله نكال الآخرة والأولى﴾ [النَّازعَات: 25]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nítorí náà, Allāhu gbá a mú pẹ̀lú ìyà ìkẹ́yìn àti àkọ́kọ́ (nípa ọ̀rọ̀ ẹnu rẹ̀ ìkẹ́yìn yìí àti àkọ́kọ́) |