Quran with Yoruba translation - Surah An-Nazi‘at ayat 46 - النَّازعَات - Page - Juz 30
﴿كَأَنَّهُمۡ يَوۡمَ يَرَوۡنَهَا لَمۡ يَلۡبَثُوٓاْ إِلَّا عَشِيَّةً أَوۡ ضُحَىٰهَا ﴾
[النَّازعَات: 46]
﴿كأنهم يوم يرونها لم يلبثوا إلا عشية أو ضحاها﴾ [النَّازعَات: 46]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ní ọjọ́ tí wọ́n máa rí i, wọn máa dà bí ẹni pé wọn kò lò tayọ ìrọ̀lẹ́ tàbí ìyálẹ̀ta (ọjọ́) kan lọ (nílé ayé) |