Quran with Yoruba translation - Surah ‘Abasa ayat 3 - عَبَسَ - Page - Juz 30
﴿وَمَا يُدۡرِيكَ لَعَلَّهُۥ يَزَّكَّىٰٓ ﴾
[عَبَسَ: 3]
﴿وما يدريك لعله يزكى﴾ [عَبَسَ: 3]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Kí sì l’ó máa fi mọ̀ ọ́ pé ó ṣeé ṣe kí ó ṣàfọ̀mọ́ (ara rẹ̀ kúrò nínú àìgbàgbọ́) |