Quran with Yoruba translation - Surah Al-Ghashiyah ayat 21 - الغَاشِية - Page - Juz 30
﴿فَذَكِّرۡ إِنَّمَآ أَنتَ مُذَكِّرٞ ﴾
[الغَاشِية: 21]
﴿فذكر إنما أنت مذكر﴾ [الغَاشِية: 21]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nítorí náà, ṣèrántí. Ìwọ kúkú ni olùṣèràntí |