Quran with Yoruba translation - Surah Yusuf ayat 55 - يُوسُف - Page - Juz 13
﴿قَالَ ٱجۡعَلۡنِي عَلَىٰ خَزَآئِنِ ٱلۡأَرۡضِۖ إِنِّي حَفِيظٌ عَلِيمٞ ﴾
[يُوسُف: 55]
﴿قال اجعلني على خزائن الأرض إني حفيظ عليم﴾ [يُوسُف: 55]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Yūsuf) sọ pé: “Fi mí ṣe aláṣẹ àwọn ọrọ̀ ìlú, dájúdájú alámòjúútó onímọ̀ ni mí.” |