Quran with Yoruba translation - Surah Al-hijr ayat 15 - الحِجر - Page - Juz 14
﴿لَقَالُوٓاْ إِنَّمَا سُكِّرَتۡ أَبۡصَٰرُنَا بَلۡ نَحۡنُ قَوۡمٞ مَّسۡحُورُونَ ﴾
[الحِجر: 15]
﴿لقالوا إنما سكرت أبصارنا بل نحن قوم مسحورون﴾ [الحِجر: 15]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni dájúdájú wọ́n á wí pé: “Wọ́n kúkú lo ìṣíjú fún wa ni. Ńṣe ni wọ́n ń dan wá.” |