Quran with Yoruba translation - Surah Al-hijr ayat 16 - الحِجر - Page - Juz 14
﴿وَلَقَدۡ جَعَلۡنَا فِي ٱلسَّمَآءِ بُرُوجٗا وَزَيَّنَّٰهَا لِلنَّٰظِرِينَ ﴾
[الحِجر: 16]
﴿ولقد جعلنا في السماء بروجا وزيناها للناظرين﴾ [الحِجر: 16]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni A kúkú fi àwọn ibùsọ̀ (ìràwọ̀) sínú sánmọ̀ (ayé). A sì ṣe é ní ọ̀ṣọ́ fún àwọn olùwòran |