Quran with Yoruba translation - Surah Al-hijr ayat 25 - الحِجر - Page - Juz 14
﴿وَإِنَّ رَبَّكَ هُوَ يَحۡشُرُهُمۡۚ إِنَّهُۥ حَكِيمٌ عَلِيمٞ ﴾
[الحِجر: 25]
﴿وإن ربك هو يحشرهم إنه حكيم عليم﴾ [الحِجر: 25]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú Olúwa rẹ, Òun l’Ó máa kó wọn jọ. Dájúdájú Òun ni Ọlọ́gbọ́n, Onímọ̀ |