Quran with Yoruba translation - Surah Al-hijr ayat 26 - الحِجر - Page - Juz 14
﴿وَلَقَدۡ خَلَقۡنَا ٱلۡإِنسَٰنَ مِن صَلۡصَٰلٖ مِّنۡ حَمَإٖ مَّسۡنُونٖ ﴾
[الحِجر: 26]
﴿ولقد خلقنا الإنسان من صلصال من حمإ مسنون﴾ [الحِجر: 26]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú A ṣẹ̀dá ènìyàn láti ara amọ̀ t’ó ń dún koko, t’ó ti pàwọ̀dà |