Quran with Yoruba translation - Surah Al-hijr ayat 27 - الحِجر - Page - Juz 14
﴿وَٱلۡجَآنَّ خَلَقۡنَٰهُ مِن قَبۡلُ مِن نَّارِ ٱلسَّمُومِ ﴾
[الحِجر: 27]
﴿والجان خلقناه من قبل من نار السموم﴾ [الحِجر: 27]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àti pé àlùjànnú, A ṣẹ̀dá rẹ̀ ṣíwájú (ènìyàn) láti ara iná alátẹ́gùn gbígbóná tí kò ní èéfín |