Quran with Yoruba translation - Surah Al-hijr ayat 48 - الحِجر - Page - Juz 14
﴿لَا يَمَسُّهُمۡ فِيهَا نَصَبٞ وَمَا هُم مِّنۡهَا بِمُخۡرَجِينَ ﴾
[الحِجر: 48]
﴿لا يمسهم فيها نصب وما هم منها بمخرجين﴾ [الحِجر: 48]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wàhálà kan kò níí bá wọn nínú rẹ̀. Wọn kò sì níí mú wọn jáde kúrò nínú rẹ̀ |