Quran with Yoruba translation - Surah Al-hijr ayat 49 - الحِجر - Page - Juz 14
﴿۞ نَبِّئۡ عِبَادِيٓ أَنِّيٓ أَنَا ٱلۡغَفُورُ ٱلرَّحِيمُ ﴾
[الحِجر: 49]
﴿نبئ عبادي أني أنا الغفور الرحيم﴾ [الحِجر: 49]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Fún àwọn ẹrúsìn Mi ní ìró pé dájúdájú Èmi ni Aláforíjìn, Àṣàkẹ́-ọ̀run |