Quran with Yoruba translation - Surah Al-hijr ayat 58 - الحِجر - Page - Juz 14
﴿قَالُوٓاْ إِنَّآ أُرۡسِلۡنَآ إِلَىٰ قَوۡمٖ مُّجۡرِمِينَ ﴾
[الحِجر: 58]
﴿قالوا إنا أرسلنا إلى قوم مجرمين﴾ [الحِجر: 58]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n sọ pé: "Dájúdájú Wọ́n rán wa níṣẹ́ sí ìjọ ẹlẹ́ṣẹ̀ ni |