Quran with Yoruba translation - Surah Al-hijr ayat 6 - الحِجر - Page - Juz 14
﴿وَقَالُواْ يَٰٓأَيُّهَا ٱلَّذِي نُزِّلَ عَلَيۡهِ ٱلذِّكۡرُ إِنَّكَ لَمَجۡنُونٞ ﴾
[الحِجر: 6]
﴿وقالوا ياأيها الذي نـزل عليه الذكر إنك لمجنون﴾ [الحِجر: 6]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n wí pé: “Ìwọ tí Wọ́n sọ al-Ƙur’ān kalẹ̀ fún, dájúdájú wèrè ni ẹ́ |