Quran with Yoruba translation - Surah Al-hijr ayat 70 - الحِجر - Page - Juz 14
﴿قَالُوٓاْ أَوَلَمۡ نَنۡهَكَ عَنِ ٱلۡعَٰلَمِينَ ﴾
[الحِجر: 70]
﴿قالوا أو لم ننهك عن العالمين﴾ [الحِجر: 70]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n wí pé: “Ǹjẹ́ àwa kò ti kọ̀ fún ọ (nípa gbígba àlejò) àwọn ẹ̀dá?” |