Quran with Yoruba translation - Surah Maryam ayat 19 - مَريَم - Page - Juz 16
﴿قَالَ إِنَّمَآ أَنَا۠ رَسُولُ رَبِّكِ لِأَهَبَ لَكِ غُلَٰمٗا زَكِيّٗا ﴾
[مَريَم: 19]
﴿قال إنما أنا رسول ربك لأهب لك غلاما زكيا﴾ [مَريَم: 19]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Mọlāika) sọ pé: “Èmi ni Òjíṣẹ́ Olúwa rẹ, (Ó rán mi sí ọ) pé kí n̄g fún ọ ní ọmọkùnrin mímọ́ kan.” |