Quran with Yoruba translation - Surah Maryam ayat 18 - مَريَم - Page - Juz 16
﴿قَالَتۡ إِنِّيٓ أَعُوذُ بِٱلرَّحۡمَٰنِ مِنكَ إِن كُنتَ تَقِيّٗا ﴾
[مَريَم: 18]
﴿قالت إني أعوذ بالرحمن منك إن كنت تقيا﴾ [مَريَم: 18]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Mọryam) sọ pé: “Èmi sá di Àjọkẹ́-ayé kúrò lọ́dọ̀ rẹ, tí o bá jẹ́ olùbẹ̀rù (Allāhu).” |