Quran with Yoruba translation - Surah Maryam ayat 20 - مَريَم - Page - Juz 16
﴿قَالَتۡ أَنَّىٰ يَكُونُ لِي غُلَٰمٞ وَلَمۡ يَمۡسَسۡنِي بَشَرٞ وَلَمۡ أَكُ بَغِيّٗا ﴾
[مَريَم: 20]
﴿قالت أنى يكون لي غلام ولم يمسسني بشر ولم أك بغيا﴾ [مَريَم: 20]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ó sọ pé: "Báwo ni mo ṣe máa ní ọmọ nígbà tí abara kan kò fọwọ́ kàn mí, tí èmi kò sì jẹ́ alágbèrè |