Quran with Yoruba translation - Surah Ta-Ha ayat 125 - طه - Page - Juz 16
﴿قَالَ رَبِّ لِمَ حَشَرۡتَنِيٓ أَعۡمَىٰ وَقَدۡ كُنتُ بَصِيرٗا ﴾
[طه: 125]
﴿قال رب لم حشرتني أعمى وقد كنت بصيرا﴾ [طه: 125]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Ó) máa wí pé: “Olúwa mi, nítorí kí ni O fi gbé mi dìde ní afọ́jú? Mo ti jẹ́ olùríran tẹ́lẹ̀!” |