Quran with Yoruba translation - Surah Ta-Ha ayat 65 - طه - Page - Juz 16
﴿قَالُواْ يَٰمُوسَىٰٓ إِمَّآ أَن تُلۡقِيَ وَإِمَّآ أَن نَّكُونَ أَوَّلَ مَنۡ أَلۡقَىٰ ﴾
[طه: 65]
﴿قالوا ياموسى إما أن تلقي وإما أن نكون أول من ألقى﴾ [طه: 65]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Àwọn òpìdán) wí pé: “Mūsā, ìwọ ni o máa kọ́kọ́ ju (ọ̀pá sílẹ̀ ni) tàbí àwa ni a óò kọ́kọ́ jù ú sílẹ̀.” |