Quran with Yoruba translation - Surah Al-Anbiya’ ayat 1 - الأنبيَاء - Page - Juz 17
﴿ٱقۡتَرَبَ لِلنَّاسِ حِسَابُهُمۡ وَهُمۡ فِي غَفۡلَةٖ مُّعۡرِضُونَ ﴾
[الأنبيَاء: 1]
﴿اقترب للناس حسابهم وهم في غفلة معرضون﴾ [الأنبيَاء: 1]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ìṣírò-iṣẹ́ súnmọ́ fún àwọn ènìyàn, wọ́n sì wà nínú ìfọ́núfọ́ra, tí wọ́n ń gbúnrí (kúrò níbi òdodo) |